Grandma and the Moon’s Hidden Secret (Yoruba)

4,500.00

Àdùkẹ́ ń gbé pẹ̀ lú àwọn òbí òbí rẹ̀ ní ìlú Ìbàdàn, Ìyá Àgbà ló sì fẹ́ràn jùlọ lágbàáyé.

Ó fẹ ́ràn kí Ìyá Àgbà máa kọrin fún àti bí wọ́n ṣe máa ń fun ní kókóró láti inú ìsọ̀ wọn.

Ní ọjọ́ kan, Àdùkẹ́ dé láti ilé-ìwé, ṣùgbọ́ n kò rí Ìyá Àgbà níbì kankan! Àdùkẹ́ ò mọ ìdí tí

Ìyá Àgbà ò le padà wá mọ́. Nígbà náà ni àntí Yímíká sọ àṣírí kan fún.

Ṣé lóòótọ́ ni ó lè rí Ìyá Àgbà nínú òṣùpá tí ó bá ṣe ojú rẹ̀ tínńtín?

Available on backorder